|
Aljebra ni eka imo isiro ti o n jemo nipa opo, ibasepo ati opoiye. Oruko aljebra wa lati inu iwe ti onimo isiro ara ile Persia, Muhammad bin Mūsā al-Khwārizmī ko pelu akole (ni ede arabu كتاب الجبر والمقابلة) Al-Kitab al-Jabr wa-l-Muqabala (to tumosi Iwe ekunrere fun isesiro nipa sisetan ati sisebamu). Eyi fi ona isojutu fun awon idogba alatele ati idogba alagbarameji han.
Awon eka aljebra
Aljebra pin si orisirisi eka wonyi:
Aljebra Ipilese
|