|
Article on other languages:
|
Irin je àdàlú ni pataki julo idẹ pelu akoonu adú larin 0.2 and 1.7 or 2.04% ni iwuwosi. Adu ni o dinwoju lati se adalu mo idẹ sugbon a tun le lo adalu awon apilese miran manganisi, kromiomu, banadiomu ati wolframu.[1] Adu ati awon apilese miran n sise bi imule sinsin lati dena ifo ninu atomu ayonu. References
Article keywords: irin news, africa angola irin, |
This article is from Wikipedia. All text is available under the terms of the GNU Free Documentation License.